Ina ku o
Native Text
Ina ku o fi eru boju, ogede ku fomo re ropo. Bi aladi o si nile omo ni jogun ebu omo ni ko jogun ewa lodo gbogbo wa.English Translation
Fire quenched, it made ash it's covering, banana died, it's succeeded by it's offspring. The children shall inherit our beauty